معلومات المواد باللغة العربية

Abdur-rahman Adunola Abdul-wahab - Fonran ohun

Onka awon ohun amulo: 1

  • Yoruba

    Oludanileko : Abdur-rahman Adunola Abdul-wahab Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

    Ibanisoro yi da lori oro nipa adiokan Imam Abu Haniifa, biotile je wipe olubanisoro menu ba adiokan awon Imaamu mereerin. Ohun ti o si se okunfa eleyi ni bi apa kan ninu awon alaimokan ni awujo se npe Imaam Abu Haniifa ni keeferi nitori awon iruju kan ti o nbe fun won nipa adiokan re. Eleyi ni oniwaasi yi se alaye re ni ekunrere, ki Olohun fi se awon Musulumi ni anfaani.